Jẹ́nẹ́sísì 11:27, 28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Ìtàn Térà nìyí. Térà bí Ábúrámù, Náhórì àti Háránì; Háránì sì bí Lọ́ọ̀tì.+ 28 Háránì kú nígbà tí Térà bàbá rẹ̀ ṣì wà láàyè, ní ilẹ̀ tí wọ́n ti bí i, ní Úrì+ ti àwọn ará Kálídíà.+
27 Ìtàn Térà nìyí. Térà bí Ábúrámù, Náhórì àti Háránì; Háránì sì bí Lọ́ọ̀tì.+ 28 Háránì kú nígbà tí Térà bàbá rẹ̀ ṣì wà láàyè, ní ilẹ̀ tí wọ́n ti bí i, ní Úrì+ ti àwọn ará Kálídíà.+