-
Jẹ́nẹ́sísì 13:5, 6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Lọ́ọ̀tì, tó ń bá Ábúrámù rìnrìn àjò, pẹ̀lú ní àwọn àgùntàn, màlúù àti àwọn àgọ́. 6 Wọn ò sì lè jọ wà níbì kan náà torí ilẹ̀ náà ò gba gbogbo wọn; ohun ìní wọn ti pọ̀ gan-an débi pé wọn ò lè jọ máa gbé pọ̀ mọ́.
-