Jẹ́nẹ́sísì 26:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Torí náà, ó mọ pẹpẹ kan síbẹ̀, ó sì ké pe orúkọ Jèhófà.+ Ísákì pàgọ́ rẹ̀ síbẹ̀,+ àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ sì gbẹ́ kànga kan síbẹ̀.
25 Torí náà, ó mọ pẹpẹ kan síbẹ̀, ó sì ké pe orúkọ Jèhófà.+ Ísákì pàgọ́ rẹ̀ síbẹ̀,+ àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ sì gbẹ́ kànga kan síbẹ̀.