Jẹ́nẹ́sísì 26:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Tí àwọn ọkùnrin ibẹ̀ bá ń béèrè nípa ìyàwó rẹ̀, ó máa ń sọ pé: “Àbúrò+ mi ni.” Ẹ̀rù ń bà á láti sọ pé “Ìyàwó mi ni,” nítorí ó sọ pé, “Àwọn ọkùnrin ibẹ̀ lè pa mí torí Rèbékà,” torí ó rẹwà gan-an.+
7 Tí àwọn ọkùnrin ibẹ̀ bá ń béèrè nípa ìyàwó rẹ̀, ó máa ń sọ pé: “Àbúrò+ mi ni.” Ẹ̀rù ń bà á láti sọ pé “Ìyàwó mi ni,” nítorí ó sọ pé, “Àwọn ọkùnrin ibẹ̀ lè pa mí torí Rèbékà,” torí ó rẹwà gan-an.+