Sáàmù 104:5, 6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ó ti gbé ayé kalẹ̀ sórí ìpìlẹ̀ rẹ̀;+A kì yóò ṣí i nípò* títí láé àti láéláé.+ 6 O fi ibú omi bò ó bí aṣọ.+ Omi náà bo àwọn òkè.
5 Ó ti gbé ayé kalẹ̀ sórí ìpìlẹ̀ rẹ̀;+A kì yóò ṣí i nípò* títí láé àti láéláé.+ 6 O fi ibú omi bò ó bí aṣọ.+ Omi náà bo àwọn òkè.