-
Jẹ́nẹ́sísì 19:28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 Nígbà tó wo apá ibi tí Sódómù àti Gòmórà wà àti gbogbo ilẹ̀ agbègbè náà, ó rí ohun tó ṣẹlẹ̀. Ó rí èéfín tó ṣú dùdù tó ń lọ sókè ní ilẹ̀ náà, ó sì dà bí èéfín tó máa ń jáde látinú iná ìléru!+
-