2 Kíróníkà 20:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Àwọn kan wá sọ fún Jèhóṣáfátì pé: “Ọ̀pọ̀ èèyàn ti wá láti agbègbè òkun,* láti Édómù,+ kí wọ́n lè bá ọ jà, wọ́n sì wà ní Hasasoni-támárì, ìyẹn Ẹ́ń-gédì.”+
2 Àwọn kan wá sọ fún Jèhóṣáfátì pé: “Ọ̀pọ̀ èèyàn ti wá láti agbègbè òkun,* láti Édómù,+ kí wọ́n lè bá ọ jà, wọ́n sì wà ní Hasasoni-támárì, ìyẹn Ẹ́ń-gédì.”+