Jóṣúà 17:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Jóṣúà fún wọn lésì pé: “Tó bá jẹ́ pé ẹ pọ̀ tó bẹ́ẹ̀, ẹ lọ sínú igbó, kí ẹ sì ṣán ibì kan fún ara yín níbẹ̀, ní ilẹ̀ àwọn Pérísì+ àti àwọn Réfáímù,+ tó bá jẹ́ pé agbègbè olókè Éfúrémù+ ti kéré jù fún yín.”
15 Jóṣúà fún wọn lésì pé: “Tó bá jẹ́ pé ẹ pọ̀ tó bẹ́ẹ̀, ẹ lọ sínú igbó, kí ẹ sì ṣán ibì kan fún ara yín níbẹ̀, ní ilẹ̀ àwọn Pérísì+ àti àwọn Réfáímù,+ tó bá jẹ́ pé agbègbè olókè Éfúrémù+ ti kéré jù fún yín.”