Lúùkù 1:72, 73 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 72 láti ṣàánú lórí ọ̀rọ̀ àwọn baba ńlá wa, kó sì rántí májẹ̀mú mímọ́ rẹ̀,+ 73 ohun tó búra fún Ábúráhámù baba ńlá wa,+
72 láti ṣàánú lórí ọ̀rọ̀ àwọn baba ńlá wa, kó sì rántí májẹ̀mú mímọ́ rẹ̀,+ 73 ohun tó búra fún Ábúráhámù baba ńlá wa,+