Jẹ́nẹ́sísì 26:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Lálẹ́ ọjọ́ yẹn, Jèhófà fara hàn án ní òru, ó sì sọ pé: “Èmi ni Ọlọ́run Ábúráhámù+ bàbá rẹ. Má bẹ̀rù,+ torí mo wà pẹ̀lú rẹ, èmi yóò bù kún ọ, màá sì mú kí ọmọ* rẹ pọ̀ torí Ábúráhámù ìránṣẹ́+ mi.”
24 Lálẹ́ ọjọ́ yẹn, Jèhófà fara hàn án ní òru, ó sì sọ pé: “Èmi ni Ọlọ́run Ábúráhámù+ bàbá rẹ. Má bẹ̀rù,+ torí mo wà pẹ̀lú rẹ, èmi yóò bù kún ọ, màá sì mú kí ọmọ* rẹ pọ̀ torí Ábúráhámù ìránṣẹ́+ mi.”