Jẹ́nẹ́sísì 13:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ábúrámù sì ń gbé inú àgọ́. Nígbà tó yá, ó lọ ń gbé láàárín àwọn igi ńlá Mámúrè,+ tó wà ní Hébúrónì;+ ó sì mọ pẹpẹ kan síbẹ̀ fún Jèhófà.+ Jẹ́nẹ́sísì 14:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Lẹ́yìn náà, ọkùnrin kan tó sá àsálà wá sọ fún Ábúrámù tó jẹ́ Hébérù. Nígbà yẹn, ó ń gbé* láàárín àwọn igi ńlá Mámúrè ọmọ Ámórì,+ arákùnrin Éṣíkólì àti Ánérì.+ Àwọn ọkùnrin yìí máa ń ran Ábúrámù lọ́wọ́.
18 Ábúrámù sì ń gbé inú àgọ́. Nígbà tó yá, ó lọ ń gbé láàárín àwọn igi ńlá Mámúrè,+ tó wà ní Hébúrónì;+ ó sì mọ pẹpẹ kan síbẹ̀ fún Jèhófà.+
13 Lẹ́yìn náà, ọkùnrin kan tó sá àsálà wá sọ fún Ábúrámù tó jẹ́ Hébérù. Nígbà yẹn, ó ń gbé* láàárín àwọn igi ńlá Mámúrè ọmọ Ámórì,+ arákùnrin Éṣíkólì àti Ánérì.+ Àwọn ọkùnrin yìí máa ń ran Ábúrámù lọ́wọ́.