ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 40:29
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 29 Ó ń fún ẹni tó ti rẹ̀ ní agbára,

      Ó sì ń fún àwọn tí kò lókun* ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ okun.+

  • Mátíù 19:26
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 26 Jésù bá tẹjú mọ́ wọn, ó sì sọ pé: “Lójú èèyàn, èyí kò ṣeé ṣe, àmọ́ ohun gbogbo ṣeé ṣe fún Ọlọ́run.”+

  • Lúùkù 1:36, 37
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 36 Wò ó! Èlísábẹ́tì mọ̀lẹ́bí rẹ náà ti lóyún ọmọkùnrin kan, ní ọjọ́ ogbó rẹ̀, oyún rẹ̀ sì ti pé oṣù mẹ́fà báyìí, ẹni táwọn èèyàn ń pè ní àgàn; 37 torí pé kò sí ìkéde kankan tí kò ní ṣeé ṣe* fún Ọlọ́run.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́