Jẹ́nẹ́sísì 25:5, 6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Lẹ́yìn náà, Ábúráhámù fún Ísákì + ní gbogbo ohun tó ní, 6 àmọ́ Ábúráhámù fún àwọn ọmọ tí àwọn wáhàrì* rẹ̀ bí fún un ní ẹ̀bùn. Nígbà tó ṣì wà láàyè, ó ní kí wọ́n máa lọ sí apá ìlà oòrùn kúrò lọ́dọ̀ Ísákì ọmọ+ rẹ̀, sí ilẹ̀ Ìlà Oòrùn.
5 Lẹ́yìn náà, Ábúráhámù fún Ísákì + ní gbogbo ohun tó ní, 6 àmọ́ Ábúráhámù fún àwọn ọmọ tí àwọn wáhàrì* rẹ̀ bí fún un ní ẹ̀bùn. Nígbà tó ṣì wà láàyè, ó ní kí wọ́n máa lọ sí apá ìlà oòrùn kúrò lọ́dọ̀ Ísákì ọmọ+ rẹ̀, sí ilẹ̀ Ìlà Oòrùn.