-
Jẹ́nẹ́sísì 22:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Lẹ́yìn náà, Ábúráhámù pa dà sọ́dọ̀ àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀, wọ́n gbéra, wọ́n sì jọ pa dà sí Bíá-ṣébà;+ Ábúráhámù sì ń gbé ní Bíá-ṣébà.
-