Gálátíà 3:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Bí ìwé mímọ́ ṣe rí i ṣáájú pé Ọlọ́run máa pe àwọn èèyàn àwọn orílẹ̀-èdè ní olódodo nípasẹ̀ ìgbàgbọ́, ó kéde ìhìn rere náà fún Ábúráhámù ṣáájú pé: “Ipasẹ̀ rẹ ni gbogbo orílẹ̀-èdè yóò fi rí ìbùkún gbà.”+
8 Bí ìwé mímọ́ ṣe rí i ṣáájú pé Ọlọ́run máa pe àwọn èèyàn àwọn orílẹ̀-èdè ní olódodo nípasẹ̀ ìgbàgbọ́, ó kéde ìhìn rere náà fún Ábúráhámù ṣáájú pé: “Ipasẹ̀ rẹ ni gbogbo orílẹ̀-èdè yóò fi rí ìbùkún gbà.”+