Jẹ́nẹ́sísì 11:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Térà pé ẹni àádọ́rin (70) ọdún, ó sì bí Ábúrámù,+ Náhórì+ àti Háránì. Jẹ́nẹ́sísì 11:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Ábúrámù àti Náhórì fẹ́ ìyàwó. Orúkọ ìyàwó Ábúrámù ni Sáráì,+ orúkọ ìyàwó Náhórì sì ni Mílíkà,+ ọmọbìnrin Háránì, bàbá Mílíkà àti Ísíkà.
29 Ábúrámù àti Náhórì fẹ́ ìyàwó. Orúkọ ìyàwó Ábúrámù ni Sáráì,+ orúkọ ìyàwó Náhórì sì ni Mílíkà,+ ọmọbìnrin Háránì, bàbá Mílíkà àti Ísíkà.