Hébérù 11:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Síbẹ̀, tó bá jẹ́ pé wọ́n ṣì ń rántí ibi tí wọ́n ti kúrò ni,+ àyè ì bá ṣí sílẹ̀ fún wọn láti pa dà.
15 Síbẹ̀, tó bá jẹ́ pé wọ́n ṣì ń rántí ibi tí wọ́n ti kúrò ni,+ àyè ì bá ṣí sílẹ̀ fún wọn láti pa dà.