Jẹ́nẹ́sísì 3:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ni ojú àwọn méjèèjì bá là, wọ́n sì wá rí i pé ìhòòhò ni àwọn wà. Torí náà, wọ́n so ewé ọ̀pọ̀tọ́ pọ̀, wọ́n sì ṣe bàǹtẹ́ fún ara wọn.+
7 Ni ojú àwọn méjèèjì bá là, wọ́n sì wá rí i pé ìhòòhò ni àwọn wà. Torí náà, wọ́n so ewé ọ̀pọ̀tọ́ pọ̀, wọ́n sì ṣe bàǹtẹ́ fún ara wọn.+