Jẹ́nẹ́sísì 48:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ó wá súre fún Jósẹ́fù, ó sì sọ pé:+ “Ọlọ́run tòótọ́, tí àwọn bàbá mi Ábúráhámù àti Ísákì bá rìn,+Ọlọ́run tòótọ́ tó ń bójú tó mi ní gbogbo ọjọ́ ayé mi títí dòní,+
15 Ó wá súre fún Jósẹ́fù, ó sì sọ pé:+ “Ọlọ́run tòótọ́, tí àwọn bàbá mi Ábúráhámù àti Ísákì bá rìn,+Ọlọ́run tòótọ́ tó ń bójú tó mi ní gbogbo ọjọ́ ayé mi títí dòní,+