-
Jẹ́nẹ́sísì 24:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Jẹ́ kó ṣẹlẹ̀ pé ọ̀dọ́bìnrin tí mo bá sọ fún pé, ‘Jọ̀ọ́, sọ ìṣà omi rẹ kalẹ̀, kí n lè mu omi,’ tó sì fèsì pé, ‘Gba omi, màá sì tún fún àwọn ràkúnmí rẹ lómi,’ kí ó jẹ́ ẹni tí wàá yàn fún Ísákì ìránṣẹ́ rẹ; kí èyí sì jẹ́ kí n mọ̀ pé o ti fi ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ hàn sí ọ̀gá mi.”
-