Jẹ́nẹ́sísì 35:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Nígbà tó yá, Dèbórà+ tó jẹ́ olùtọ́jú Rèbékà kú, wọ́n sì sin ín sí ìsàlẹ̀ Bẹ́tẹ́lì lábẹ́ igi ràgàjì* kan. Torí náà, ó pè é ní Aloni-bákútì.*
8 Nígbà tó yá, Dèbórà+ tó jẹ́ olùtọ́jú Rèbékà kú, wọ́n sì sin ín sí ìsàlẹ̀ Bẹ́tẹ́lì lábẹ́ igi ràgàjì* kan. Torí náà, ó pè é ní Aloni-bákútì.*