Jẹ́nẹ́sísì 24:67 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 67 Lẹ́yìn náà, Ísákì mú Rèbékà wá sínú àgọ́ Sérà ìyá rẹ̀.+ Ó fi Rèbékà ṣe aya; ó nífẹ̀ẹ́ rẹ̀+ gan-an, Ísákì sì rí ìtùnú lẹ́yìn tí ìyá+ rẹ̀ kú.
67 Lẹ́yìn náà, Ísákì mú Rèbékà wá sínú àgọ́ Sérà ìyá rẹ̀.+ Ó fi Rèbékà ṣe aya; ó nífẹ̀ẹ́ rẹ̀+ gan-an, Ísákì sì rí ìtùnú lẹ́yìn tí ìyá+ rẹ̀ kú.