-
Jẹ́nẹ́sísì 20:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Ábímélékì wá pe Ábúráhámù, ó sì sọ fún un pé: “Kí lo ṣe sí wa yìí? Ẹ̀ṣẹ̀ wo ni mo ṣẹ̀ ọ́, tí o fi fẹ́ fi ìyà ẹ̀ṣẹ̀ tó pọ̀ tó báyìí jẹ èmi àti àwọn èèyàn mi? Ohun tí o ṣe sí mi yìí ò dáa.”
-