Jẹ́nẹ́sísì 24:34, 35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Ó wá sọ pé: “Ìránṣẹ́+ Ábúráhámù ni mí. 35 Jèhófà sì ti bù kún ọ̀gá mi gan-an, ó ti mú kó lọ́rọ̀ gidigidi torí ó fún un ní àwọn àgùntàn àti màlúù, fàdákà àti wúrà, àwọn ìránṣẹ́kùnrin àti ìránṣẹ́bìnrin, àwọn ràkúnmí àti kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́.+
34 Ó wá sọ pé: “Ìránṣẹ́+ Ábúráhámù ni mí. 35 Jèhófà sì ti bù kún ọ̀gá mi gan-an, ó ti mú kó lọ́rọ̀ gidigidi torí ó fún un ní àwọn àgùntàn àti màlúù, fàdákà àti wúrà, àwọn ìránṣẹ́kùnrin àti ìránṣẹ́bìnrin, àwọn ràkúnmí àti kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́.+