Jẹ́nẹ́sísì 21:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Ìdí nìyẹn tó fi pe ibẹ̀ ní Bíá-ṣébà,*+ torí pé àwọn méjèèjì búra níbẹ̀.