-
Jẹ́nẹ́sísì 27:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Jọ̀ọ́, lọ síbi tí agbo ẹran wà, kí o sì mú méjì nínú àwọn ọmọ ewúrẹ́ tó dáa jù wá fún mi, kí n lè fi wọ́n se oúnjẹ tó dùn fún bàbá rẹ, bó ṣe máa ń fẹ́ kó rí.
-