-
Jẹ́nẹ́sísì 27:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Lẹ́yìn náà, Rèbékà mú aṣọ tó dáa jù tó jẹ́ ti Ísọ̀ ọmọ rẹ̀ àgbà, èyí tó ní nínú ilé, ó sì wọ̀ ọ́ fún Jékọ́bù+ ọmọ rẹ̀ tó jẹ́ àbúrò.
-