ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 25:23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 Jèhófà sì sọ fún un pé: “Orílẹ̀-èdè méjì ló wà nínú ikùn+ rẹ, èèyàn méjì tó yàtọ̀ síra máa tinú rẹ+ jáde; orílẹ̀-èdè kan máa lágbára ju ìkejì+ lọ, ẹ̀gbọ́n sì máa sin àbúrò.”+

  • Jẹ́nẹ́sísì 27:29
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 29 Kí àwọn èèyàn máa sìn ọ́, kí àwọn orílẹ̀-èdè sì máa tẹrí ba fún ọ. Kí o di ọ̀gá lórí àwọn arákùnrin rẹ, kí àwọn ọmọ ìyá rẹ sì máa tẹrí ba fún ọ.+ Kí ègún wà lórí ẹnikẹ́ni tó bá gégùn-ún fún ọ, kí ìbùkún sì wà lórí ẹnikẹ́ni tó bá ń súre fún ọ.”+

  • Róòmù 9:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Kì í ṣe ìgbà yẹn nìkan, àmọ́ ó tún ṣẹlẹ̀ nígbà tí Rèbékà lóyún ìbejì fún ọkùnrin kan, ìyẹn Ísákì baba ńlá wa;+

  • Róòmù 9:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 a sọ fún un pé: “Ẹ̀gbọ́n ni yóò jẹ́ ẹrú àbúrò.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́