Jẹ́nẹ́sísì 3:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Nínú gbogbo ẹranko tí Jèhófà Ọlọ́run dá, ejò+ ló máa ń ṣọ́ra jù.* Ó sọ fún obìnrin náà pé: “Ṣé òótọ́ ni Ọlọ́run sọ pé ẹ kò gbọ́dọ̀ jẹ nínú èso gbogbo igi inú ọgbà?”+
3 Nínú gbogbo ẹranko tí Jèhófà Ọlọ́run dá, ejò+ ló máa ń ṣọ́ra jù.* Ó sọ fún obìnrin náà pé: “Ṣé òótọ́ ni Ọlọ́run sọ pé ẹ kò gbọ́dọ̀ jẹ nínú èso gbogbo igi inú ọgbà?”+