-
Jẹ́nẹ́sísì 30:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
30 Nígbà tí Réṣẹ́lì rí i pé òun ò bí ọmọ kankan fún Jékọ́bù, ó bẹ̀rẹ̀ sí í jowú ẹ̀gbọ́n rẹ̀, ó sì ń sọ fún Jékọ́bù pé: “Fún mi ní ọmọ, àìjẹ́ bẹ́ẹ̀, màá kú.”
-