-
Jẹ́nẹ́sísì 29:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Nígbà tí ilẹ̀ mọ́, Jékọ́bù rí i pé Líà ni! Torí náà, ó sọ fún Lábánì pé: “Kí lo ṣe fún mi yìí? Ṣebí torí Réṣẹ́lì ni mo ṣe sìn ọ́? Kí ló dé tí o fi tàn mí jẹ?”+
-
-
Jẹ́nẹ́sísì 31:39Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
39 Mi ò mú ẹran èyíkéyìí tí ẹranko+ ti fà ya wá fún ọ. Èmi ni mò ń forí fá àdánù rẹ̀. Ì báà jẹ́ ọ̀sán tàbí òru ni wọ́n jí ẹran, o máa ń sọ pé kí n dí i pa dà fún ọ.
-