ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 35:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Jékọ́bù wá sọ fún agbo ilé rẹ̀ àti gbogbo àwọn tó wà pẹ̀lú rẹ̀ pé: “Ẹ mú àwọn ọlọ́run àjèjì tó wà láàárín yín+ kúrò, kí ẹ wẹ ara yín mọ́, kí ẹ pààrọ̀ aṣọ yín,

  • Jóṣúà 24:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Jóṣúà sọ fún gbogbo àwọn èèyàn náà pé: “Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì sọ nìyí, ‘Òdìkejì Odò* ni àwọn baba ńlá yín+ gbé ní ọ̀pọ̀ ọdún sẹ́yìn,+ ìyẹn Térà bàbá Ábúráhámù àti bàbá Náhórì, àwọn ọlọ́run míì ni wọ́n sì jọ́sìn.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́