-
Jẹ́nẹ́sísì 27:43Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
43 Torí náà, ọmọ mi, ṣe ohun tí mo bá sọ fún ọ. Gbéra, kí o sì sá lọ sọ́dọ̀ Lábánì arákùnrin mi ní Háránì.+
-
-
Jẹ́nẹ́sísì 28:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Lọ sí Padani-árámù, ní ilé Bẹ́túẹ́lì bàbá ìyá rẹ, kí o sì fẹ́ ìyàwó níbẹ̀ láàárín àwọn ọmọbìnrin Lábánì,+ arákùnrin ìyá rẹ.
-