Jóṣúà 24:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Jóṣúà wá kó gbogbo ẹ̀yà Ísírẹ́lì jọ sí Ṣékémù, ó pe àwọn àgbààgbà Ísírẹ́lì, àwọn olórí wọn, àwọn onídàájọ́ àti àwọn aṣojú,+ wọ́n sì dúró síwájú Ọlọ́run tòótọ́.
24 Jóṣúà wá kó gbogbo ẹ̀yà Ísírẹ́lì jọ sí Ṣékémù, ó pe àwọn àgbààgbà Ísírẹ́lì, àwọn olórí wọn, àwọn onídàájọ́ àti àwọn aṣojú,+ wọ́n sì dúró síwájú Ọlọ́run tòótọ́.