2 Sámúẹ́lì 13:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ábúsálómù kò bá Ámínónì sọ nǹkan kan, ì báà jẹ́ búburú tàbí rere; nítorí Ábúsálómù kórìíra+ Ámínónì torí pé ó ti kó ẹ̀gàn bá Támárì+ àbúrò rẹ̀.
22 Ábúsálómù kò bá Ámínónì sọ nǹkan kan, ì báà jẹ́ búburú tàbí rere; nítorí Ábúsálómù kórìíra+ Ámínónì torí pé ó ti kó ẹ̀gàn bá Támárì+ àbúrò rẹ̀.