-
Jẹ́nẹ́sísì 24:53Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
53 Ìránṣẹ́ náà wá bẹ̀rẹ̀ sí í mú àwọn nǹkan tí wọ́n fi fàdákà àti wúrà ṣe àti aṣọ, ó kó wọn fún Rèbékà, ó sì fún arákùnrin rẹ̀ àti ìyá rẹ̀ ní àwọn nǹkan iyebíye.
-