Jẹ́nẹ́sísì 28:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ó wá pe orúkọ ibẹ̀ ní Bẹ́tẹ́lì,* àmọ́ Lúsì+ ni ìlú náà ń jẹ́ tẹ́lẹ̀. Jẹ́nẹ́sísì 31:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Èmi ni Ọlọ́run tòótọ́ tó bá ọ sọ̀rọ̀ ní Bẹ́tẹ́lì,+ níbi tí o ti da òróró sórí òpó tí o gbé sílẹ̀, tí o sì ti jẹ́ ẹ̀jẹ́ fún mi.+ Wá gbéra báyìí, kí o kúrò ní ilẹ̀ yìí, kí o sì pa dà sí ilẹ̀ tí wọ́n ti bí ọ.’”+
13 Èmi ni Ọlọ́run tòótọ́ tó bá ọ sọ̀rọ̀ ní Bẹ́tẹ́lì,+ níbi tí o ti da òróró sórí òpó tí o gbé sílẹ̀, tí o sì ti jẹ́ ẹ̀jẹ́ fún mi.+ Wá gbéra báyìí, kí o kúrò ní ilẹ̀ yìí, kí o sì pa dà sí ilẹ̀ tí wọ́n ti bí ọ.’”+