Ẹ́kísódù 13:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 kí ẹ ya gbogbo àkọ́bí ọkùnrin* sọ́tọ̀ fún Jèhófà, pẹ̀lú gbogbo àkọ́bí ẹran ọ̀sìn yín tó jẹ́ akọ. Jèhófà ló ni àwọn akọ.+
12 kí ẹ ya gbogbo àkọ́bí ọkùnrin* sọ́tọ̀ fún Jèhófà, pẹ̀lú gbogbo àkọ́bí ẹran ọ̀sìn yín tó jẹ́ akọ. Jèhófà ló ni àwọn akọ.+