-
Jẹ́nẹ́sísì 27:39Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
39 Ísákì bàbá rẹ̀ wá sọ fún un pé:
“Wò ó, ibi tó jìnnà sí àwọn ilẹ̀ tó lọ́ràá ní ayé àti ibi tó jìnnà sí ìrì tó ń sẹ̀ láti ọ̀run ni wàá máa gbé.+
-