Ẹ́kísódù 15:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ní àkókò yẹn, ẹ̀rù yóò ba àwọn séríkí* Édómù, Àwọn alágbára tó ń ṣàkóso Móábù* yóò gbọ̀n rìrì.+ Ọkàn gbogbo àwọn tó ń gbé ní Kénáánì yóò domi.+
15 Ní àkókò yẹn, ẹ̀rù yóò ba àwọn séríkí* Édómù, Àwọn alágbára tó ń ṣàkóso Móábù* yóò gbọ̀n rìrì.+ Ọkàn gbogbo àwọn tó ń gbé ní Kénáánì yóò domi.+