1 Kíróníkà 1:42 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 42 Àwọn ọmọ Ésérì+ ni Bílíhánì, Sááfánì àti Ékánì. Àwọn ọmọ Díṣánì ni Úsì àti Áránì.+