Jẹ́nẹ́sísì 44:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Nígbà tí Júdà+ àti àwọn arákùnrin rẹ̀ lọ sínú ilé Jósẹ́fù, ó ṣì wà níbẹ̀; wọ́n sì wólẹ̀ síwájú rẹ̀.+ Jẹ́nẹ́sísì 45:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 “Ẹ tètè pa dà sọ́dọ̀ bàbá mi, kí ẹ sì sọ fún un pé, ‘Ohun tí Jósẹ́fù ọmọ rẹ sọ nìyí: “Ọlọ́run ti fi mí ṣe olúwa lórí gbogbo Íjíbítì.+ Máa bọ̀ lọ́dọ̀ mi. Tètè máa bọ̀.+
14 Nígbà tí Júdà+ àti àwọn arákùnrin rẹ̀ lọ sínú ilé Jósẹ́fù, ó ṣì wà níbẹ̀; wọ́n sì wólẹ̀ síwájú rẹ̀.+
9 “Ẹ tètè pa dà sọ́dọ̀ bàbá mi, kí ẹ sì sọ fún un pé, ‘Ohun tí Jósẹ́fù ọmọ rẹ sọ nìyí: “Ọlọ́run ti fi mí ṣe olúwa lórí gbogbo Íjíbítì.+ Máa bọ̀ lọ́dọ̀ mi. Tètè máa bọ̀.+