Jẹ́nẹ́sísì 4:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Lẹ́yìn náà, Kéènì sọ fún Ébẹ́lì àbúrò rẹ̀ pé: “Jẹ́ ká lọ sí oko.” Nígbà tí wọ́n sì wà nínú oko, Kéènì lu Ébẹ́lì àbúrò rẹ̀, ó sì pa á.+ Jẹ́nẹ́sísì 4:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ọlọ́run wá sọ pé: “Kí lo ṣe yìí? Tẹ́tí kó o gbọ́ mi! Ẹ̀jẹ̀ àbúrò rẹ ń ké jáde sí mi láti inú ilẹ̀.+ Jẹ́nẹ́sísì 42:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ni Rúbẹ́nì bá sọ fún wọn pé: “Ṣebí mo sọ fún yín pé, ‘Ẹ má ṣẹ ọmọ náà,’ àmọ́ ṣé ẹ dá mi lóhùn?+ Ẹ̀san+ ti wá dé báyìí torí ẹ̀jẹ̀ rẹ̀.”
8 Lẹ́yìn náà, Kéènì sọ fún Ébẹ́lì àbúrò rẹ̀ pé: “Jẹ́ ká lọ sí oko.” Nígbà tí wọ́n sì wà nínú oko, Kéènì lu Ébẹ́lì àbúrò rẹ̀, ó sì pa á.+
10 Ọlọ́run wá sọ pé: “Kí lo ṣe yìí? Tẹ́tí kó o gbọ́ mi! Ẹ̀jẹ̀ àbúrò rẹ ń ké jáde sí mi láti inú ilẹ̀.+
22 Ni Rúbẹ́nì bá sọ fún wọn pé: “Ṣebí mo sọ fún yín pé, ‘Ẹ má ṣẹ ọmọ náà,’ àmọ́ ṣé ẹ dá mi lóhùn?+ Ẹ̀san+ ti wá dé báyìí torí ẹ̀jẹ̀ rẹ̀.”