Jẹ́nẹ́sísì 42:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Wọ́n sọ fún ara wọn pé: “Ó dájú pé torí Jósẹ́fù+ ni ìyà yìí ṣe ń jẹ wá, torí a rí ìdààmú tó bá a* nígbà tó bẹ̀ wá pé ká yọ́nú sí òun, àmọ́ a ò dá a lóhùn. Ìdí nìyẹn tí wàhálà yìí fi dé bá wa.”
21 Wọ́n sọ fún ara wọn pé: “Ó dájú pé torí Jósẹ́fù+ ni ìyà yìí ṣe ń jẹ wá, torí a rí ìdààmú tó bá a* nígbà tó bẹ̀ wá pé ká yọ́nú sí òun, àmọ́ a ò dá a lóhùn. Ìdí nìyẹn tí wàhálà yìí fi dé bá wa.”