Jẹ́nẹ́sísì 37:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ísírẹ́lì nífẹ̀ẹ́ Jósẹ́fù ju gbogbo àwọn ọmọ+ rẹ̀ yòókù lọ torí pé ìgbà tó darúgbó ló bí i, ó sì ṣe aṣọ kan tó ṣàrà ọ̀tọ̀* fún un.
3 Ísírẹ́lì nífẹ̀ẹ́ Jósẹ́fù ju gbogbo àwọn ọmọ+ rẹ̀ yòókù lọ torí pé ìgbà tó darúgbó ló bí i, ó sì ṣe aṣọ kan tó ṣàrà ọ̀tọ̀* fún un.