Jẹ́nẹ́sísì 39:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 Wọ́n wá mú Jósẹ́fù lọ sí Íjíbítì,+ Pọ́tífárì+ ará Íjíbítì tó jẹ́ òṣìṣẹ́ láàfin Fáráò àti olórí ẹ̀ṣọ́ sì rà á lọ́wọ́ àwọn ọmọ Íṣímáẹ́lì+ tó mú un lọ síbẹ̀.
39 Wọ́n wá mú Jósẹ́fù lọ sí Íjíbítì,+ Pọ́tífárì+ ará Íjíbítì tó jẹ́ òṣìṣẹ́ láàfin Fáráò àti olórí ẹ̀ṣọ́ sì rà á lọ́wọ́ àwọn ọmọ Íṣímáẹ́lì+ tó mú un lọ síbẹ̀.