Jẹ́nẹ́sísì 46:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Orúkọ àwọn ọmọkùnrin Ísírẹ́lì tó wá sí Íjíbítì + nìyí, Jékọ́bù àti àwọn ọmọ rẹ̀: Rúbẹ́nì+ ni àkọ́bí Jékọ́bù.
8 Orúkọ àwọn ọmọkùnrin Ísírẹ́lì tó wá sí Íjíbítì + nìyí, Jékọ́bù àti àwọn ọmọ rẹ̀: Rúbẹ́nì+ ni àkọ́bí Jékọ́bù.