ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 26:22-25
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 Kí o ṣe férémù mẹ́fà sí ẹ̀yìn àgọ́ ìjọsìn náà, lápá ìwọ̀ oòrùn.+ 23 Kí o fi férémù méjì ṣe òpó sí igun méjèèjì ẹ̀yìn àgọ́ ìjọsìn náà. 24 Kí férémù náà ní igi méjì láti ìsàlẹ̀ dé òkè, níbi òrùka àkọ́kọ́. Ohun tí o máa ṣe sí méjèèjì nìyẹn, wọ́n á sì jẹ́ òpó ní igun méjèèjì. 25 Ó máa jẹ́ férémù mẹ́jọ àti ìtẹ́lẹ̀ oníhò wọn mẹ́rìndínlógún (16) tí wọ́n fi fàdákà ṣe, ìtẹ́lẹ̀ méjì tó ní ihò máa wà lábẹ́ férémù kan, ìtẹ́lẹ̀ méjì tó ní ihò sì máa wà lábẹ́ ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn férémù yòókù.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́