ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 26:31, 32
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 31 “Kí o fi fọ́nrán òwú aláwọ̀ búlúù, òwú aláwọ̀ pọ́pù, òwú aláwọ̀ rírẹ̀dòdò àti aṣọ ọ̀gbọ̀ lílọ́ tó dáa ṣe aṣọ ìdábùú.+ Kí o kó iṣẹ́ sí i lára, kí iṣẹ́ náà jẹ́ àwòrán àwọn kérúbù. 32 Kí o gbé e kọ́ sára òpó igi bọn-ọ̀n-ní mẹ́rin tí wọ́n fi wúrà bò. Kí o fi wúrà ṣe àwọn ìkọ́ wọn. Kí àwọn òpó náà wà lórí ìtẹ́lẹ̀ mẹ́rin tó ní ihò tí wọ́n fi fàdákà ṣe.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́