-
Ẹ́kísódù 25:29Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
29 “Kí o tún ṣe àwọn abọ́ ìjẹun rẹ̀, àwọn ife rẹ̀, àwọn ṣágo àti àwọn abọ́ rẹ̀ tí wọ́n á máa da ọrẹ ohun mímu látinú rẹ̀. Kí o fi ògidì wúrà ṣe wọ́n.+
-